Portada de Eleduwa - Barry Jhay

Eleduwa Letra - Barry Jhay

Favorito
Esta canción todavía no tiene video¿Conoces el video oficial? Agrégalo y ayuda a todos.
Agregar video +3 pts

Letra oficial

Eleduwa Lyrics

(Mur-Mur-Murderer)

Ijọ buruku lo n'ijọ tuntun

Baba, ṣo n gbọ oun aiyé n sọ?


Eleduwa, ẹyin l'akọkọ ninu gbogbo nkan

Kẹ to d'aiye at'ọrun

And that why me I put you first, in everything I do

O ma ma ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ


Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey

Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'

Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ

Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?


Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin

Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun

L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede

L'atoni lọ, ma gbe ori'lẹ yi ṣe oun rere


Ẹyin to laiye ẹ gb'ohun mi ṣ'aṣẹ pa

I be ọmọ aiye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o

Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o

K'aiye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu

Ay, ti n ba lu n ṣe ni ko ma dun


Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey

Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'

Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ

Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?


Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin

Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun

L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede

L'atoni lọ, ma gbe or'ilẹ yii ṣe oun rere


L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede

L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere

Letra aportada por Nilmey
¿Viste un error en la letra? Corregir letra
Ayúdanos a mejorar esta letra y te damos el crédito

¿Qué te hace sentir "Eleduwa"?

Sé el primero en reaccionar a esta canción

¿Te encanta la letra de Eleduwa? ¡Compártela con tus amigos!

Comentarios (0)

Tu correo es privado, no se publica. Si lo pones, te avisamos cuando alguien te responda.
0/1000

Aún no hay comentarios. ¡Sé la primera persona en contar qué significa esta canción para ti!

Información del sencillo

"Eleduwa" es una canción interpretada por Barry Jhay, publicada en el álbum Barrystar Vol. 1. 

Fecha de lanzamiento: 10 de abril del año 2025. 

¿Puedes mejorar esta descripción?Cuéntanos más de la canción. Si la aprobamos, ganas puntos.
Mejorar descripción +20 pts
¿Cuándo salió "Eleduwa" de Barry Jhay?

10 de abril del año 2025

¿En qué álbum está "Eleduwa" de Barry Jhay?

Barrystar Vol. 1

Créditos de producción

Todavía no tenemos los créditos de esta canciónCada dato que aprobemos (productores, escritores, distribuidora o sello) te da puntos.
Agregar créditos +3 pts c/u

Top 5 canciones de Barry Jhay

See Me See god (SMSG) Ẹ ma ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro, Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu, Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn, Ẹni j'alangba n tutu, a kó warapa, Oh-ah, oh-ah-ah-ah, Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah, Oh-wa, oh, wa-wa-wa, (Nobody's perfect, nobody's perfect), Ye, k'iku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi… What a Life Hm, when you talk, I dey ṣa, (V-V-Vsticks), What a li-li-li-li-life, what a life, See, I got voices, I got voices, I got voices in my head, Telling me, 'Let the fire burn', Telling me that I'm one of all, And the fire is burning o, is burning o, is burning in my head, How I feel inside of me, saying… Rest Ẹni Ọlọhun fe l'Ọlọhun ni yan, omọ Ibunu Adamọ le f'apa janu o, Ẹ simi ariwo, Chalé rest, no be your face dey upon dollar bill, I never lose my cool to dead people, Sipping on my gin and juice (Shark, more), Boys on my ass, niggas stay by my booze, I don't snooze, so I ain't got shit to lose, Ọmọ, i… Lost Na-ahn-ahn, oh-no, Yeah-yeah, yeah (Yo Dibs), Oh-no, The way you do me, say, Bo ṣe n ṣe mi gàn-gàn, Bo ṣe n ṣe mi, me, I no fit to explain, no-nuh, I'll be your daddy, you go be my mummy, Together, we go gather dey, And there's nothing, for me to take me away from you, The way you do me, you dey mak… Eskelebebe I no dey do pass myself, I no dey bite wetin I no—, I wanna pull all bag with my big bag with my bloody shoes (Oh-oh), Ọtọtọ lọrọ o, no be you, wetin dey do me dey do you, Say, I no dey do pass myself, I no dey bite wetin I no fit chew, I no fit afford to go broke na why I dey do wetin I need to do,…
Comunidad LETRASBOOM.COM

¡Únete! Es gratis y toma 10 segundos

  • Guarda tus canciones y artistas favoritos
  • Comenta, reacciona y que todos vean tu perfil
  • Envía letras y corrige errores para ayudar a todos
  • Gana puntos, sube de nivel y colecciona insignias

Lee la letra completa de Eleduwa interpretada por Barry Jhay. Descubre el video musical, la información del sencillo y explora más letras, álbumes y colaboraciones del artista en LETRASBOOM.COM.